Yoruba Hymn APA 502 - Olorun, gb’ okan mi loni

Yoruba Hymn APA 502 - Olorun, gb’ okan mi loni

 Yoruba Hymn  APA 502 - Olorun, gb’ okan mi loni

APA 502

1. Olorun, gb’ okan mi loni,

 Si ma se ni Tire’;

 Ki mma sako lodo Re mo,

 Ki mma ye lodo Re.


2. Wo! Mo wole buruburu

 L’ese agbelebu;

 Kan gbogo ese mi mo ‘gi,

 Ki Krist’ j’ohun gbogbo.


3. F’ ore-ofe orun fun mi,

 Si se mi ni Tire;

 Ki nle r’ oju Re t’o logo,

 Ki mma sin n’ite Re.


4. K’ero, oro, at’ ise mi

 Je Tire titi lai;

 Ki nfi gbogb’ aiye mi sin O,

 K’ iku je isimi.


5. Ogo gbogbo ni fun Baba,

 Ogo ni fun Omo,

 Ogo ni fun Emi Mimo,

 Titi ainipekun. Amin.Yoruba Hymn  APA 502 - Olorun, gb’ okan mi loni

This is Yoruba Anglican hymns, APA 502- Olorun, gb’ okan mi loni . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post