Yoruba Hymn APA 501 - Ji, okan mi, dide giri

Yoruba Hymn APA 501 - Ji, okan mi, dide giri

Yoruba Hymn  APA 501 - Ji, okan mi, dide giri

APA 501

 1. Ji, okan mi, dide giri,

 Ma lepa nso kikan:

 F’ itara sure ije yi’

 Fun ade ti ki sa.


2. Awosanma eleri wa,

 Ti nwon nf’ oju sun O

 Gbagbe irin atehinwa,

 Sa ma te siwaju.


3. Olorun nf’ ohun igbera

 Ke si o lat’ oke:

 Tikare l’O npin ere na,

 T’o nnoga lati wo.


4. Olugbala ’Wo l’o mu mi

 Bere ije mi yi;

 Nigbat’ a ba de mi l’ ade,

 Ngo wole lese Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 501 - Ji, okan mi, dide giri

This is Yoruba Anglican hymns, APA 501- Ji, okan mi, dide giri . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post