Yoruba Hymn APA 504 - Jesu f’ ara han nitoto

Yoruba Hymn APA 504 - Jesu f’ ara han nitoto

 Yoruba Hymn  APA 504 - Jesu f’ ara han nitoto

APA 504

1. Jesu f’ ara han nitoto,

 Nibi ase ’yawo;

 Oluwa, awa be O, wa,

 F’ ara Re han nihin.


2. Fi ibukun Re fun awon

 Ti o dawopo yi;

 F’ ojurere wo ’dapo won,

 Si bukun egbe won.


3. F’ ebun ife kun aiya won,

 Fun won n’ itelorun;

 Fi alafia Re kun won,

 Si busi ini won.


4. F’ ife mimo so won d’ okan,

 Kin won f’ ife Kristi

 Mu aniyan ile fere,

 Nipa ajumose.


5. Je kin won ran ’ra won lowo,

 Ninu igbgbo won;

 Kin won si ni omo rere,

 Ti y’o gbe ’le won ro! Amin.Yoruba Hymn  APA 504 - Jesu f’ ara han nitoto

This is Yoruba Anglican hymns, APA 504- Jesu f’ ara han nitoto . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post