Yoruba Hymn APA 505 - Simi le Oluwa – e gbo

Yoruba Hymn APA 505 - Simi le Oluwa – e gbo

Yoruba Hymn  APA 505 - Simi le Oluwa – e gbo

APA 505

 1. Simi le Oluwa – e gbo

 Orin duru orun –

 Simi le ’fe Re ailopin,

 Si duro je.


2. Simi, iwo oko t’o gba

 Iyawo re loni;

 Ninu Jesu, ’yawo re ni

 Titi aiye.


3. Iwo ti a fa owo re

 F’oko n’nu ile yi,

 Simi; Baba f’edidi Re

 S’ileri nyin.


4. E simi, enyin ore won,

 T’e wa ba won pejo;

 Olorun won ati ti nyin

 Gba ohun won.


5. Simi; Jesu Oko Ijo

 Duro ti nyin nihin;

 Ninu idapo nyin, O nfa

 Ijo mora.


6. E simi: - Adaba Mimo,

 M’ oro Re se n’nu wa –

 Simi le ’fe Re ailopin,

 Si duro je. Amin.Yoruba Hymn  APA 505 - Simi le Oluwa – e gbo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 505-  Simi le Oluwa – e gbo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post