Yoruba Hymn APA 507 - Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi

Yoruba Hymn APA 507 - Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi

Yoruba Hymn  APA 507 - Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi

APA 507

 1. Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi,

 ’Wo ni mo gbekele;

 Oro Re n’ iranlowo mi,

 Emi alailera.

 Nko ni ejo kan lati ro,

 Ko s’ ohun ti ngo wi;

 Eyi to, pe Jesu mi ku,

 Jesu mi ku fun mi.


2. Igba iji ’danwo ba nja,

 T’ota ndojuko mi,

 Ite anu n’ isadi mi,

 Nibe n’ ireti mi.

 Okan mi yio sa to wa,

 ’Gba ’banuje ba de;

 Ayo okan mi l’eyi pe,

 Jesu mi ku fun mi.


3. Larin iyonu t’o wuwo,

 T’enia ko le gba;

 Larin ibanuje okan,

 Ati ’rora ara;

 Kil’o le funni n’ isimi,

 Ati suru b’ eyi?

 T’o ns’ eleri l’ okan mi pe,

 Jesu mi ku fun mi.


4. ’Gba ohun Re ba si pase

 K’ ara yi dibaje,

 Ti emi mi, b’ isan omi,

 Ba si san koja lo,

 B’ ohun mi ko tile jale,

 Nigbana, Oluwa,

 Fun mi n’ipa kin le wipe,

 Jesu mi ku fun mi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 507 - Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 507- Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals




Post a Comment (0)
Previous Post Next Post