Yoruba Hymn APA 517 - Bi agogo ofo t’ a nlu

Yoruba Hymn APA 517 - Bi agogo ofo t’ a nlu

Yoruba Hymn  APA 517 -  Bi agogo ofo t’ a nlu

APA 517

 1. Bi agogo ofo t’ a nlu,

 Ti npe okan yi koja lo,

 K’ olukuluku bi ’ra re,

 “Mo ha setan b’ iku pe mi!”


2. “Ki nf’ ohun ti mo fe sile,

 Kin lo sid’ ite idajo?

 Ki ngbohun Onidajo na,

 Ti y’o so ipo mi fun mi.”


3. Ara mi ha gba, b’ o wipe,

 “Lo lodo mi eni egun?

 Sinu ina t’ a ti pese

 Fun Esu ati ogun re?”


4. Jesu Oluwa, jo gba mi,

 Iwo ni mo gbeke mi le;

 Ko mi ki nr’ ona ewu yi,

 Ko mi ki mba O gbe titi. Amin.



Yoruba Hymn  APA 517 -  Bi agogo ofo t’ a nlu

This is Yoruba Anglican hymns, APA 517- Bi agogo ofo t’ a nlu . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post