Yoruba Hymn APA 516 - Igba asale ti dun to

Yoruba Hymn APA 516 - Igba asale ti dun to

Yoruba Hymn  APA 516 - Igba asale ti dun to

APA 516

 1. Igba asale ti dun to!

 Ti ara tu ohun gbogbo:

 ’Gbat’ itansan orun ale

 Ba ntanmole s’ ohun gbogbo!


2. Beni ’kehin onigbagbo,

 On a simi l’ alafia;

 Igbagbo to gbona janjan

 A mole ninu okan re.


3. Imole kan mo loju re,

 Erin sib o ni enu re;

 O nf’ ede t’ ahon wa ko mo

 Soro ogo t’o sunmole.


4. Itansan ’mole t’ orun wa,

 Lati gba niyanju lona;

 Awon angel duro yika

 Lati gbe lo s’ibugbe won.


5. Oluwa, je k’ a lo bayi,

 K’a ba O yo, k’a r’ oju Re;

 Te aworan Re s’ okan wa,

 Si ko wa b’ a ti ba O rin. Amin.Yoruba Hymn  APA 516 - Igba asale ti dun to

This is Yoruba Anglican hymns, APA 516-  Igba asale ti dun to . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post