Yoruba Hymn APA 519 - Ranse Olorun, seun

Yoruba Hymn APA 519 - Ranse Olorun, seun

Yoruba Hymn  APA 519 - Ranse Olorun, seun

APA 519

 1. “Ranse Olorun, seun;

 Simi n’nu lala re;

 Iwo ti ja, o si segun;

 Bo s’ ayo Baba re.”

 Ohun na de loru,

 O dide lati gbo;

 Ofa iku si wo l’ ara,

 O subu, ko beru.


2. Igbe ta loganjo,

 “Pade Olorun re.”

 O ji, o ri Balogun re;

 N’n’ adura on ’gbagbo,

 Okan re nde wiri,

 O bo amo sile,

 Gbat’ ile mo, ago ara

 Si sun sule l’ oku.


3. ’Rora iku koja,

 Lala at’ ise tan:

 Ojo ogun jaja pari,

 Okan re r’ alafia;

 Omo-ogun Krist’, o seun!

 Ma korin ayo sa!

 Simi lodo Olugbala,

 Simi titi aiye. Amin.Yoruba Hymn  APA 519 - Ranse Olorun, seun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 519- Ranse Olorun, seun . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post