Yoruba Hymn APA 525 - Ara, iwo si| waju wa lo

Yoruba Hymn APA 525 - Ara, iwo si| waju wa lo

Yoruba Hymn  APA 525 - Ara, iwo si| waju wa lo

APA 525

 1. Ara, iwo si| waju wa lo,

 Emi re mi| mo si ti fo lo,

 Sibiti ko ni | s’ ekun mo;

 Ti | ko si irora.


2. O bo lowo|  eru ara

 Ati lowo|  aniyan aiye:

 Nib’ eni-buburu|  ye yonu,

 Ti a| lare si simi.


3. ’Wo ti rin ajo|  aiye ja,

 O ti|  gb’ agbelebu re;

 Krist ti fie se re|  le ona,

 Lati|  de ib’ isimi.


4. Bi Lasaru|  l’o si sun,

 L’ a| kaiya Baba re,

 Nib ’eni-buburu|  ye yonu,

 Ti a| lare si simi.


5. Ese ko le | ba o je mo,

 I| yemeji d’ opin;

 Igbagbo re ni| nu Kristi

 At’ Emi|  ko ni ye mo lai.


6. L’ orun lohun|  n’ iwo o ba

 Awon ore|  t’o ti lo saju;

 Nib’ eni-buburu | ye yonu,

 Ti a| lare si simi.


7. Alufa ti wi ni| sisiyi pe,

 Eru f’eru, e| rupe f’erupe;

 Awa si ko e| rupe bo o,

 A si | sami s’ori re.


8. Sugbon emi re|  ti fo lo,

 So| do awon mimo;

 Nib’ eni-buburu|  ye yonu,

 Ti a| lare si simi.


9. ’Gbat’ Olu| wa ba sip e

 A| wa t’o ku lehin;

 Oluwa wa, |  awa be O,

 K’ai| ye ma ba wa je,


10. K’ olukuluku wa, b’ a| ra yi,

 Le ri|  aye lodo Re,

 Nib’ eni-buburu | ye yonu,

 Ti a| lare si simi. Amin.Yoruba Hymn  APA 525 - Ara, iwo si| waju wa lo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 525- Ara, iwo si| waju wa lo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post