Yoruba Hymn APA 526 - Isin Jesu ni ’funni

Yoruba Hymn APA 526 - Isin Jesu ni ’funni

Yoruba Hymn  APA 526 - Isin Jesu ni ’funni

APA 526

 1. Isin Jesu ni ’funni

 L’ayo toto, l’aiye yi;

 Isin Jesu ni ’funni

 N’ itunu ninu iku.


2. Lehin ’ku ayo na mbe,

 Ti ko ni d’ opin lailai;

 K’ Olorun sa je t’emi,

 Ayo mi ki o l’opin. Amin.Yoruba Hymn  APA 526 - Isin Jesu ni ’funni

This is Yoruba Anglican hymns, APA 526- Isin Jesu ni ’funni. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post