Yoruba Hymn APA 552 - E je k’a f’ inu didun

Yoruba Hymn APA 552 - E je k’a f’ inu didun

Yoruba Hymn  APA 552 -  E je k’a f’ inu didun

APA 552

 1. E je k’a f’ inu didun

 Yin Oluwa Olore;

 Anu Re, O wa titi,

 Lododo dajudaju.


2. On, nipa agbara Re,

 F’ imole s’aiye titun;

 Anu Re, o wa titi,

 Lododo dajudaju.


3. O mbo gbogb’ eda ’laye,

 O npese fun aini won;

 Anu Re, o wa titi,

 Lododo dajudaju.


4. O bukun ayanfe Re,

 Li aginju iparun;

 Anu Re, o wa titi,

 Lododo dajudaju.


5. E je k’a f’ inu didun,

 Yin Oluwa Olore;

 Anu Re, o wa titi,

 Lododo dajudaju. Amin.Yoruba Hymn  APA 552 -  E je k’a f’ inu didun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 552-  E je k’a f’ inu didun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post