Yoruba Hymn APA 575 - A fi ipile yi le’ le

Yoruba Hymn APA 575 - A fi ipile yi le’ le

Yoruba Hymn  APA 575 - A fi ipile yi le’ le

APA 575

 1. A fi ipile yi le’ le,

 Ni oruko Re Oluwa,

 Awa mbe o, Oluwa wa.

 Ma toju ibi mimo yi.


2. Gba enia Re ba nwa O,

 T’ elese nwa O n’ ile yi,

 Gbo, Olorun lat’ orun wa,

 F’ ese won ji won, Olorun.


3. ’Gb’ awon Alufa ba nwasu

 Ihinrere ti Omo Re;

 Ni oruko Re, Oluwa,

 Ma sise iyanu nla Re.


4. ’Gb’ awon omode ba si nko

 Hoseanna si Oba won;

 Ki Angel ba won ko pelu,

 K’ orun at’ aiye jo gberin.


5. Jehofah o ha ba ni gbe,

 Ni aiye buburu wa yi?

 Jesu o ha je Oba wa,

 Emi o ha simi nihin?


6. Ma je ki ogo Re kuro

 Ninu ile ti a nko yi;

 Se ’joba Re ni okan wa,

 Si te ite Re sinu wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 575 - A fi ipile yi le’ le

This is Yoruba Anglican hymns, APA 575-  A fi ipile yi le’ le. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post