Yoruba Hymn APA 574 - Oro alafia

Yoruba Hymn APA 574 - Oro alafia

 Yoruba Hymn  APA 574 - Oro alafia

APA 574

1. Oro alafia,

 La fi sin nyin, ara,

 K’ alafia bi odo nla,

 Ma ba nyin lo.


2. N’nu oro adura,

 A f’ awon ara wa

 Le iso Oluwa lowo,

 Ore toto.


3. Oro ife didun,

 L’a p’ odigbose;

 Ife wa ati t’ Olorun,

 Y’o ba won gbe.


4. Oro gbagbo lile,

 Ni igbekele wa;

 Pe Oluwa y’o se ranwo,

 Nigba gbogbo.


5. Odigbose, ara,

 N’ ife at’ igbagbo;

 Tit’ ao fi tun pade loke,

 N’ ile wa orun. Amin.Yoruba Hymn  APA 574 - Oro alafia

This is Yoruba Anglican hymns, APA 574-  APA 574 - Oro alafia. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post