Yoruba Hymn APA 576 - Kristi n’ ipile wa

Yoruba Hymn APA 576 - Kristi n’ ipile wa

 Yoruba Hymn  APA 576 - Kristi n’ ipile wa

APA 576

1. Kristi n’ ipile wa,

 Lori Re lao kole;

 Awon mimo nikan,

 L’o ngb’ agbala orun.

 Ireti wa

 T’ ore aiye

 T’ ayo ti mbo,

 Wa n’nu ’fe Re.


2. Agbala mimo yi,

 Y’o ho f’ orin iyin,

 Ao korin iyin si,

 Metalokan mimo.

 Be lao f’ orin

 Ayo kede

 Oruko Re

 Titi aiye.


3. Olorun Olore,

 Fiyesini nihin;

 Lati gba eje wa,

 At’ ebe wa gbogbo;

 K’o si f’ opo

 Bukun dahun

 Adura wa

 Nigbagbogbo.


4. Nihin, je k’ ore Re

 T’a ntoro l’at’ orun,

 Bo s’ ori wa lekan,

 Ko ma sit un lo mo.

 Tit’ ojo na

 T’ao s’akojo

 Awon mimo

 Sib’ isimi. Amin.Yoruba Hymn  APA 576 - Kristi n’ ipile wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 576 - Kristi n’ ipile wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post