Yoruba Hymn Apa 11 - Ogo f’ Olorun l’ ale yi

Yoruba Hymn Apa 11 - Ogo f’ Olorun l’ ale yi

 Yoruba Hymn Apa 11 - Ogo f’ Olorun l’ ale yi

APA 11

1. Ogo f’ Olorun l’ ale yi

 Fun gbogbo ore imole

 So mi, Oba awon oba

 Labe ojiji iye Re.


2. Oluwa, f’ese mi ji mi,

 Nitori Omo Re loni;

 K’ emi le wa l’ Alafia,

 Pelu Iwo ati aiye.


3. Ko mi ki nwa, kin le ma wo

 Iboji tenmen b’ eni mi;

 Ko mi ki nku, kin le dide

 Ninu ogo l’ ojo dajo.


4. Je k’ okan mi le sun le O,

 K’ orun didun p’oju mi de;

 Orun ti y’o m’ ara mi le

 Kin le sin O li owuro.


5. Bi mo ba dubule laisun,

 F’ ero orun kun okan mi:

 Ma je ki nlala buburu,

 Ma je k’ ipa okun bo mi.

 

6. Yin Oluwa gbogbo eda,

 Ti mbe nisale aiye yi;

 E yin loke, eda orun,

 Yin Baba, Omo on Emi. Amin.

Yoruba Hymn Apa 11 - Ogo f’ Olorun l’ ale yi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 11 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post