Yoruba Hymn APA 33 - Ojo mefa t’ ise koja

  Yoruba Hymn  APA 33 - Ojo mefa t’ ise koja

APA 33

1. Ojo mefa t’ ise koja,

 Okan t’ isimi si bere:

 Wa, okan mi si ’simi re,

 Yo s’ ojo t’ Olorun busi.


2 Ki ’ronu at’ ope wan de,

 Bi ebo turari s’ orun;

 K’ o le fa inu didun wa,

 T’ o je t’ eni t’ o mo nikan.


3. Ibale aiya orun yi,

 L’ eri isimi t’ o l’ogo;

 T’ o wa fun enia mimo

 Opin aniyan at’ aisan.


4. Olorun, a yo si ’se Re,

 L’ oniruru t’ ogbo t’ otun;

 A fi ’yin ro anu t’ o lo,

 A ni ’reti s’eyi ti mbo.

 

5. F’ oni sisin mimo jale,

 K’o si se inu didun si;

 B’ o ti dun lati l’ojo yi

 Nireti okan ailopin? Amin.

Yoruba Hymn  APA 33 - Ojo mefa t’ ise koja

This is Yoruba Anglican hymns, APA 33 - Ojo mefa t’ ise koja. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post