Yoruba Hymn APA 115 - E yo Jesu joba

Yoruba Hymn APA 115 - E yo Jesu joba

Yoruba Hymn  APA 115 -  E yo Jesu joba

APA 115

 1. E yo Jesu joba

 ’Nu omo enia

 O da ara tubu

 O so won d’ omnira:

 K’ esu koju s’ Om’ Olorun,

 Lai f’ ota pe, ise Re nlo.


2. Ise ti ododo

 Oto, Alafia

 Fun rorun aiye wa,

 Yio tan ka kiri

 Keferi, Ju, nwon o wole

 Nwon o jeje isin yiye.


3. Agbara l’ owo Re

 Fun abo eni Re;

 Si ase giga Re

 L’ opo o kiyesi.

 Orun ayo ri ise Re.

 Ekusu rere gb’ ofin Re.


4. Irugbin t’ orun yi

 O fere d’ igi nla;

 Abukun wukara

 Ko le saitan kiri;

 Tit’ Olorun Omo tun wa

 Ko le sailo, Amin ! Amin ! Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 115 - E yo Jesu joba . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post