Yoruba Hymn APA 135 - Gbo iro efufu, lat’ ona jijin

Yoruba Hymn APA 135 - Gbo iro efufu, lat’ ona jijin

Yoruba Hymn  APA 135 - Gbo iro efufu, lat’ ona jijin

APA 135

 1. Gbo iro efufu, lat’ ona jijin;

 O nsoro ’jakadi ti ogun mimo;

 Olorun mbe fun wa, O ti soro Re,

 O sin so gbogbo nyin, “Ojise orun.”


2. Lo ! ’wo Ihinrere, ma segun titi

 Okunkun ndimole, ni gbogbo aiye;

 Osa nwole fun O, ile won si nwo,

 Gbogb’ eda bu jewo pe, ’Wo l’ Oluwa.


3. Olugbala mimo ti njoba loke,

 K’ awon om’ ogun Re ma ri O titi;

 Je k’ oro Re ma tan lat’ ile de ’le,

 Ki gbogbo agbaiye teriba fun O. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 135 - Gbo iro efufu, lat’ ona jijin . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post