Yoruba Hymn APA 139 - Iyin f’Eni Mimo julo

Yoruba Hymn APA 139 - Iyin f’Eni Mimo julo

Yoruba Hymn  APA 139 - Iyin f’Eni Mimo julo

APA 139

 1. Iyin f’Eni Mimo julo,

 Loke ati n’ile:

 Oro Re gbogbo je ’yanu,

 Gbogb’ ona Re daju.


2. Ogbon Olorun tip o to !

 Gbat’ enia subu;

 Adam keji wa s’oju ’ja,

 Ati lati gbala.


3. Ogbon ife ! pe’ran ara

 T’ o gbe Adam subu,

 Tun b’ota ja ija otun.

 K’ o ja k’o si segun


4. Ati p’ ebun t’o j’ or’ ofe

 So ara di otun;

 Olorun papa Tikare

 J’ Olorun ninu wa.


5. Ife ’yanu ! ti Eniti

 O pa ota enia,

 Ninu awo awa enia

 Je irora f’ enia.


6. Nikoko ninu ogba ni,

 Ati lori igi,

 To si ko wa lati jiya,

 To ko wa lati ku.


7. Iyin f’Eni Mimo julo,

 Loke ati n’ile:

 Oro Re gbogbo je ’yanu,

 Gbogb’ ona Re daju. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 139 -  Iyin f’Eni Mimo julo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post