Yoruba Hymn APA 149 - Jina s’ile orun

Yoruba Hymn APA 149 - Jina s’ile orun

 Yoruba Hymn  APA 149 -  Jina s’ile orun

APA 149

1. Jina s’ile orun,

 S’okan aiya Baba,

 Emi ’bukun, wa, mo ndaku,

 Mu mi re ’bi ’simi.


2. Mo fi duru mi ko

 S’ori igi willo;

 Ngo se korin ayo, gbati

 ’Wo koi t’ahon mi se ?


3. Emi mi lo sile,

 A ! mba le fo de ’be:

 Ayun re nyun mi, ’wo Sion

 Gba mo bar anti re.


4. Sodo Re mo nt’ona,

 To kun fun isoro;

 Gbawo ni ngo koj’aginju,

 De ’le awon mimo ?


5. Sunmo mi, Olorun,

 ’Wo ni mo gbekele;

 Sin mi la aginju aiye,

 Ki m’ de ’le nikehin. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 149 - Jina s’ile orun   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post