Yoruba Hymn APA 150 - Nigba nwon kehin si Sion

Yoruba Hymn APA 150 - Nigba nwon kehin si Sion

Yoruba Hymn  APA 150 -  Nigba nwon kehin si Sion

APA 150

1. Nigba nwon kehin si Sion,

 A ! opo n’iye won;

 Mo seb’ Olugbala wi pe,

 ’Wo fe ko mi pelu ?


2. T’ emi t’ okan b’ iru eyi,

 Afi b’ O di mi mu;

 Nko le se kin ma fa sehin,

 K’ emi si dabi won.


3. Mo mo, Iwo l’ o l’ agbara

 Lati gba otosi;

 Odo tani emi o lo,

 Bi mo k’ ehin si O ?


4. O da mi loju papa pe,

 Iwo ni Kristi na !

 Eni t’ o ni emi iye,

 Nipa tie je Re.


5. Ohun Re f’ isimi fun mi,

 O si l’ eru mi lo;

 Ife Re l’ o le mu mi yo

 O si to f’ okan mi.


6. Bi ’bere yi ti dun mi to,

 “Pee mi o lo bi ?”

 Oluwa, ni ’gbekele Re,

 Mo dahun pe “Beko.” Amin.



This is Yoruba Anglican hymns, APA 150- Nigba nwon kehin si Sion  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post