Yoruba Hymn APA 151 - Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re

Yoruba Hymn APA 151 - Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re

 Yoruba Hymn  APA 151 - Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re

APA 151

1. Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re,

 S’ oro Alafia;

 Gbogbo ipa mi y’o dalu

 Lati yin ore Re.


2. Fi iyonu pe mi l’ omo,

 K’ o si dariji mi;

 Ohun na yio dunmo mi,

 B’ iro orin orun.


3. Ibikibi t’ o to mi si,

 L’ emi o f’ ayo lo;

 Tayotayo l’ emi o si

 Dapo m’ awon oku.


4. ’Gba eru ebi ba koja,

 Eru mi ko si mo;

 Owo t’ o fun ’dariji ka,

 Y’o pin ade iye. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 151 - Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post