Yoruba Hymn APA 156 - Ro iponju mi, Oluwa

Yoruba Hymn APA 156 - Ro iponju mi, Oluwa

Yoruba Hymn  APA 156 - Ro iponju mi, Oluwa

APA 156

1. Ro iponju mi, Oluwa,

 Ran iranlowo Re !

 Okan mi daku fun’ gbala,

 Ise mi ki o pin ?


2. Mo rip e o dara fun mi,

 Ki Baba mi na mi;

 Iya mu mi ko ofin Re,

 Ki mgbeke mi le O.


3. Mo mo pe idajo Re to,

 Bi o tile muna;

 Iponju ti mo foriti

 O ti odo Re wa.


4. K’ emi to m’owo ina Re,

 Emi a ma sina;

 Sugbon bi mo ti k’ oro Re,

 Emi ko sako mo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 156 - Ro iponju mi, Oluwa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post