Yoruba Hymn APA 166 - Kristi t’ agbelebu l’ orin wa

Yoruba Hymn APA 166 - Kristi t’ agbelebu l’ orin wa

Yoruba Hymn  APA 166 - Kristi t’ agbelebu l’ orin wa

APA 166

 1. Kristi t’ agbelebu l’ orin wa,

 Ijinle t’ awa nso;

 O j’ egan loju awon ju,

 Were lowo Griki.


2. Sugbon okan t’ Olorun ko

 F’ ayo gba oro na;

 Nwon ri ogbon, ipa, ife,

 T’ o han n’ Oluwa won.


3. Adun oruko Re yiye

 Mu ’soji s’ okan won;

 Aigbagbo l’ohun t’ o ba ni je,

 Si ebi at’ iku.


4. Lai j’ Olorun t’ or’ ofe ka

 Bi owara ojo;

 Lasan l’ Apollos funrugbin,

 Paul si le gbin lasan. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 166-   Kristi t’ agbelebu l’ orin wa  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post