Yoruba Hymn APA 175 - Otosi elese, e wa

Yoruba Hymn APA 175 - Otosi elese, e wa

 Yoruba Hymn  APA 175 - Otosi elese, e wa

APA 175

1. Otosi elese, e wa,

 Wa ni wakati anu;

 Jesu setan lati gba nyin,

 O kun f’ anu at’ ife:

 O si le se, o mura tan, ma foiya.


2. Enyin alaini, e wa gba

 Ogo Olorun lofe,

 ’Gbagbo toto, ’ronu toto,

 Or’ofe ti o nfa wa,

 Wa ’do Jesu, laini owo, sa wa ra.


3. Ma je k’ okan nyin da nyin ro,

 Maser o ti aiye nyin;

 Gbogbo yiye t’ O mbere ni,

 Ki e sa mo aini nyin:

 ’Yi l’ O fun nyin; ’tansan Emi l’ okan.


4. Eyin t’eru npa, t’are mu,

 T’ e sonu t’e si segbe,

 Bi e duro tit’ eo fi, san

 E ki yio wa rara:

 F’ elese ni, On ko wa f’olododo.


5. Olorun goke l’awo wa,

 O nfi eje Re bebe:

 Gbe ara le patapata:

 Ma gbekele ohun mi:

 Jesu nikan l’o le s’ elese l’ore.


6. Angeli at’ awon mimo

 Nkorin ’yin Odagutan;

 Gbohungbohun Oruko Re

 Si gba gbogbo orun kan:

 Halleluya ! elese le gberin na. Amin.

 Yoruba Hymn  APA 175 - Otosi elese, e wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 175  -  Otosi elese, e wa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post