Yoruba Hymn APA 197 - W’ Olori Alufa Giga

Yoruba Hymn APA 197 - W’ Olori Alufa Giga

Yoruba Hymn  APA 197 - W’ Olori Alufa Giga

APA 197

 1. W’ Olori Alufa Giga

 B’ o ti gbe ebe wa lo;

 L’ ogba, o f’ikedun wole,

 O f’eru dojubole;

 Angeli f’idamu duro

 Lati ri Eleda be;

 Awa o ha wa l’ aigbogbe,

 T’a mo pe tori wa ni?


2. Kiki eje Jesu nikan

 L’o le yi okan pada;

 On l’o le gba wa n’nu ebi,

 On l’o le m’okan wa ro:

 Ofin at’ ikilo ko to,

 Nwon ko si le nikan se;

 Ero yi l’o le m’okan ro:

 Oluwa ku dipo mi!


3. Jesu, gbogbo itunu wa,

 Lat’ odo Re l’o ti nwa;

 Ife, ’gbagbo, reti, suru

 Gbogbo re l’eje Re ra:

 Lat’ inu ekun Re l’a ngba,

 A ko da ohun kan ni;

 Lofe n’Iwo nfi won tore

 Fun awon t’o s’ alaini. Amin.

Yoruba Hymn  APA 197 - W’ Olori Alufa Giga

This is Yoruba Anglican hymns, APA 197 -  W’ Olori Alufa Giga . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post