Yoruba Hymn APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi

Yoruba Hymn APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi

 Yoruba Hymn  APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi

APA 196

1. “Hosanna s’Omo Dafidi:”

 Hosanna! e korin!

 “Olubukun l’eniti mbo

 Loruko Oluwa.”


2. “Hosanna s’Omo Dafidi:”

 L’egbe Angeli nke;

 Gbogb’ eda, e jumo gberin,

 Hosonna s’Oba wa.


3. Hosanna! awon Heberu

 Ja im’ope s’ona ;

 Hosanna! a mu ebun wa

 Fi tun ona Re se.


4. T’agba t’ewe nke, Hosanna!

 K’ijiya Re to de;

 L’oni, a si nko Hosanna!

 B’o ti njoba loke.


5. B’o ti gba ’yin won nigbana,

 Jo, gba ebe wa yi!

 Lorun, k’a le b’Angel korin,

 Hosanna s’Oba wa. Amin.

 

Yoruba Hymn  APA 196 - Hosanna s’Omo Dafidi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 196 -  Hosanna s’Omo Dafidi  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post