Yoruba Hymn APA 214 - Leba iboji Jesu mi

Yoruba Hymn APA 214 - Leba iboji Jesu mi

Yoruba Hymn  APA 214 -  Leba iboji Jesu mi

APA 214

 1. Leba iboji Jesu mi,

 Nigbat’ okunkun bo ile,

 Awon asofo duro je.


2. Ara are jaja simi,

 Irora ati wahala

 Enit’ o jiya wa pari.


3. Iho t’a wo n’nu okuta

 Ni a te Olugbala si;

 Olorun, Eleda aiye.


4. Enyin t’ ofo se, t’e ndaro,

 Nihin n’ isimi wa fun nyin;

 Nihin, k’ ibanuje nyin pin. Amin.Yoruba Hymn  APA 214 -  Leba iboji Jesu mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 214-  Leba iboji Jesu mi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post