Yoruba Hymn APA 220 - Lo so fun gbogbo aiye

Yoruba Hymn APA 220 - Lo so fun gbogbo aiye

Yoruba Hymn  APA 220 - Lo so fun gbogbo aiye

APA 220

1. Lo so fun gbogbo aiye,

 Lo tan ihin ayo yi;

 Eti t’ o ba gbo, y’o si,

 Okan t’ o ba gbo, y’o la.


2. Jesu Olugbala wa,

 T’ a sin, fi boji sile;

 Olorun gba ebo Re,

 Ebo ese araiye.


3. O ji lati ma ku mo,

 Akobi awon t’o sun;

 Eniti o ba gba gbo

 Yio ye, b’ o tile ku.


4. Angeli! eda orun,

 E ba araiye gberin;

 Jesu Oludande ji,

 Alafia titi lai. Amin. 


Yoruba Hymn  APA 220 - Lo so fun gbogbo aiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 220-  Lo so fun gbogbo aiye   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post