Yoruba Hymn APA 222 - Oluwa ji loto

Yoruba Hymn APA 222 - Oluwa ji loto

 Yoruba Hymn  APA 222 - Oluwa ji loto

APA 222

1. Oluwa ji loto,

 Olugbala dide,

 O f’ agbara Re han.

 L’ or’ orun apadi:

N’ iberu nla; awon eso

Subu lule, nwon si daku.


2. Wo, egbe angeli

 Pade l’ ajo kikun;

 Lati gbo ase Re,

 Ati lati juba:

Nwon f’ ayo wa, nwon s info lo,

Lati orun si boji na.


3. Nwon tun fo lo s’ orun,

 Nwon mu’ hin ayo lo;

 Gbo iro orin won,

 Bi nwon si t info lo.

Orin won ni, Jesu t’ o ku,

Ti ji dide; o ji loni.


4. Enyin t’ a ra pada,

 E gberin ayo na;

 Ran iro re kiri,

 Si gbogbo agbaiye.

E ho f’ ayo. Jesu t’ o ku,

T ji dide: ki y’o ku mo.


5. Kabiyesi! Jesu!

 T’ o f’ eje Re gba wa;

 Ki iyin Re kale,

 Iwo t’ o ji dide:

A ba O ji, a si joba,

Pelu Re lai; l’ oke orun. Amin.


Yoruba Hymn  APA 222 - Oluwa ji loto

This is Yoruba Anglican hymns, APA 222- Oluwa ji loto . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post