Yoruba Hymn APA 223 - Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi

Yoruba Hymn APA 223 - Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi

 Yoruba Hymn  APA 223 - Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi

APA 223

1. “Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi;

 A sete ’ku loni, Orun di ti wa.

 ’Wo Oku d’ alaye, Oba tit’ aiye!

 Gbogb’ eda Re Jesu, ni nwon njuba Re.

 “Kabo, ojo rere,” lao ma wi titi;

 A sete ’ku loni, orun di ti wa.


2. Eleda, Oluwa, Emi alaye!

 Lat’ orun l’ o ti bojuwo ’sina wa,

Om’ Olorun papa ni ’Wo tile se,

K’ O ba le gba wa la, O di enia.

 “Kabo, ojo rere,” &c.


3. ’Wo Oluwa iye, O wa to ’ku wo;

 Lati f’ipa Re han, O sun n’ iboji;

 Wa, Eni Oloto, si m’oro Re se,

 Ojo keta Re de, jinde Oluwa!

 “Kabo, ojo rere,” &c.


4. Tu igbekun sile, t’ Esu de l’ewon,

 Awon t’o si subu, jog be won dide;

 F’ojurere Re han, je k’aiye reran.

 Tun mu ’mole wa de, ’Wo sa ni ’mole;

 “Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi;

 A sete ’ku loni, orun di ti wa. Amin.


Yoruba Hymn  APA 223 - Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 223-   Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post