Yoruba Hymn APA 227 - Oluwa ji loto

Yoruba Hymn APA 227 - Oluwa ji loto

Yoruba Hymn  APA 227 - Oluwa ji loto

APA 227

1. “Oluwa ji loto,”

 Ihin na ha s’ oto?

 Nwon ti ri p’ Olugbala ku,

 Nwon ri l’ aye pelu.


2. “Oluwa ji loto,”

 Oto ko fe ju yi;

 Anu at’ otito pade,

 Ti nwon ti ns’ ota ri.


3. “Oluwa ji loto,”

 Ise Re l’ o setan;

 A d aide onigbowo,

 A se apa iku.


4. “Oluwa ji l’ oto,”

 Boji ko le se mo;

 Awon t’ o ku si ji pelu,

 Nwon ki o si ku mo. Amin.Yoruba Hymn  APA 227 - Oluwa ji loto

This is Yoruba Anglican hymns, APA 227-  Oluwa ji loto . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post