Yoruba Hymn APA 274 - Emi Mimo sokale

Yoruba Hymn APA 274 - Emi Mimo sokale

Yoruba Hymn  APA 274 - Emi Mimo sokale

APA 274

 1. Emi Mimo sokale,

 Ba wa gbe ni aiye yi;

 Fi ohun orun han ni,

 Si ba ni sin Olorun.


2. Ese wa ni okan wa,

 Ti a ko le fi sile;

 Agbara wa ko to se,

 Bi ’Wo ko ba pelu wa.


3. Awa nfe k’ ese parun,

 L’ okan ati l’ ara wa;

 Wa, Emi Mimo, jo wa,

 K’ o we gbogbo ese nu.


4. Olorun, ’Wo l’ awa nfe,

 Fi Emi Re na fun wa;

 K’ a le pa ofin Re mo,

 K’ a si rin ni ona Re. Amin.
Yoruba Hymn  APA 274 - Emi Mimo sokale

This is Yoruba Anglican hymns, APA 274 -  Emi Mimo sokale. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post