Yoruba Hymn APA 282 - Olorun Metalokan

Yoruba Hymn APA 282 - Olorun Metalokan

Yoruba Hymn  APA 282 - Olorun Metalokan

APA 282

 1. Olorun Metalokan,

 Oba ile at’ okun;

 Gbo ti wa bi a ti nko

 Orin iyin Re.


2. ’Wo imole, lowuro,

 Tan ’mole Re yi wa ka:

 Je ki ebun rere Re

 M’ aiya wa bale.


3. ’Wo imole, nigb’ orun wo,

 K’a ri idariji gba;

 Ki Alafia orun

 F’ itura fun wa.


4. Olorun Metalokan!

 Isin wa laiye ko to!

 A nreti lati dapo

 Mo awon t’ orun. Amin.Yoruba Hymn  APA 282 - Olorun Metalokan

This is Yoruba Anglican hymns, APA 282- Olorun Metalokan   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post