Yoruba Hymn APA 281 - Baba oke Orun

Yoruba Hymn APA 281 - Baba oke Orun

Yoruba Hymn  APA 281 - Baba oke Orun

APA 281

 1. Baba oke Orun,

 T’ imole at’ ife,

 Eni ‘gbani!

 ‘Mole t’ a ko le wo,

 Ife t’ a ko le so,

 Iwo Oba airi,

 Awa yin O.


2. Kristi Omo lailai,

 ‘Wo t’o di enia,

 Olugbala:

 Eni giga julo,

 Olorun, Imole,

 Aida at’ Ailopin,

 A kepe O.


3. Iwo Emi Mimo

 T’ ina Pentikost’ Re,

 Ntan titilai;

 Mas’ aitu wa ninu,

 L’ aiye aginju yi:

 ‘Wo l’a fe, ‘Wo l’a nyin,

 A juba Re.


4. Angel’ e lu duru

 K’orin t’awa tin yin;

 Jumo dalu:

 Ogo fun Olorun,

 Metalokansoso;

 A yinn O tit’ aiye

 Ainipekun. Amin.Yoruba Hymn  APA 281 - Baba oke Orun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 281- Baba oke Orun    . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post