Yoruba Hymn APA 284 - E fi ogo fun Baba

Yoruba Hymn APA 284 - E fi ogo fun Baba

Yoruba Hymn  APA 284 - E fi ogo fun Baba

APA 284

 1. E fi ogo fun Baba,

 Nipa Eniti a wa;

 O ngbo adura ewe,

 O nf’ eti si orin won.


2. E fi ogo fun Omo,

 Kristi, ’Wo ni Oba wa;

 E wa, e korin s’ oke,

 S’ Odagutan elese.


3. Ogo fun Emi Mimo,

 Bi ojo Pentikosti;

 Ru aiya awon ewe,

 F’ orin mimo s’ ete won.


4. Ogo ni l’ oke orun,

 Fun Eni Metalokan;

 Nitori ihin rere,

 Ati ife Olorun. Amin.Yoruba Hymn  APA 284 - E fi ogo fun Baba

This is Yoruba Anglican hymns, APA 284- E fi ogo fun Baba  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post