Yoruba Hymn APA 290 - Bawo ni awon ewe wa

Yoruba Hymn APA 290 - Bawo ni awon ewe wa

Yoruba Hymn  APA 290 - Bawo ni awon ewe wa

APA 290

 1. Bawo ni awon ewe wa,

 Y’o ti ma sora won?

 Bikose “nipa ’kiyesi,

 Gege bi oro Re.”


2. ’Gba oro na wo ’nu okan,

 A tan imole ka;

 Oro na ko ope l’ ogbon,

 At’ imo Olorun.


3. Orun ni, imole wa ni,

 Amona wa l’ osan;

 Fitila ti nfonahan wa,

 Ninu ewu oru.


4. Oro Re, oto ni titi,

 Mimo ni gbogbo re:

 Amona wa l’ ojo ewe,

 Opa l’ ojo ogbo. Amin.Yoruba Hymn  APA 290 - Bawo ni awon ewe wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 290- Bawo ni awon ewe wa   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post