Yoruba Hymn APA 306 - Oluwa Olorun mi, se ’fe Re

Yoruba Hymn APA 306 - Oluwa Olorun mi, se ’fe Re

Yoruba Hymn  APA 306 - Oluwa Olorun mi, se ’fe Re

APA 306

 1. Oluwa Olorun mi, se ’fe Re:

 Nki o mi ’ra,

 Nko ni dide, ki nma ba sesi ta.

 Owo na nu,

 Ti nmu mi ro mo aiya Baba mi

 Ni isimi.


2. Okan ti njijakadi, ni Kristi

 Nfun l’ agbara;

 Iwaiya ija Re oru, ’gbati

 Ko s’ enikan,

 Ju Baba at’ Angeli rere kan

 Ti ntu ninu.


3. “Baba, ’fe mi ko, Tire ni k’a se”

 Be l’ Omo wi.

 K’ eyi je ’siri wa larin gbogbo

 Lala aiye,

 K’a le ro mo aiya Re titi lai

 Ni isimi. AminYoruba Hymn  APA 306 - Oluwa Olorun mi, se ’fe Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 306-   Oluwa Olorun mi, se ’fe Re   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post