Yoruba Hymn APA 311 - Alafia, li laiye ese yi

Yoruba Hymn APA 311 - Alafia, li laiye ese yi

Yoruba Hymn  APA 311 - Alafia, li laiye ese yi

APA 311

 1. Alafia, li laiye ese yi?

 Eje Jesu nwipe, “Alafia.”


2. Alafia, ninu opo lala?

 Lati se ife Jesu, ni ’simi.


3. Alafia, n’nu igbi banuje?

 L’ aiya Jesu ni dake roro wa.


4. Alafia, gb’ ara wa wa l’ajo?

 Ni ’pamo Jesu, iberu ko si.


5. Alafia, b ’a ko tile m’ ola?

 Sugbon a mo pe Jesu wa lailai.


6. Alafia, nigb’ akoko iku?

 Olugbala wa ti segun iku.


7. O to: jakadi aiye fere pin,

 Jesu y’o pe wa s’ orun Alafia. Amin.Yoruba Hymn  APA 311 - Alafia, li laiye ese yi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 311- Alafia, li laiye ese yi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post