Yoruba Hymn APA 314 - Jesu, Olugbala, wo mi

Yoruba Hymn APA 314 - Jesu, Olugbala, wo mi

 Yoruba Hymn  APA 314 - Jesu, Olugbala, wo mi

APA 314

1. Jesu, Olugbala, wo mi,

 Are mu mi, ara nni mi;

 Mo de lati gb’ ara le O;

 ’Wo ’simi mi.


2. Bojuwo mi, o re mi tan;

 Irin ajo na gun fun mi;

 Mo nwa ’ranwo agbara Re,

 ’Wo Ipa mi.


3. Idamu ba mi l’ona mi,

 Oru sokun, iji si nfe,

 Tan imole si ona mi,

 ’Wo ’Mole mi.


4. Gba Satani ba tafa re,

 ’Wo ni mo nwo: nko beru mo;

 Agbelebu Re l’abo mi,

 ’Wo Alafia mi.


5. Mo nikan wa leti Jordan,

 Ninu ’waiya-’ja jelo ni:

 ’Wo ki yio je k’emi ri;

 ’Wo Iye mi.


6. Gbogbo aini, ’Wo o fun mi

 Titi d’opin; l’onakona;

 Ni ’ye, ni ’ku, titi lailai,

 ’Wo Gbogbo mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 314 - Jesu, Olugbala, wo mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 314-  Jesu, Olugbala, wo mi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post