Yoruba Hymn APA 326 - Ona ara l’Olorun wa

Yoruba Hymn APA 326 - Ona ara l’Olorun wa

Yoruba Hymn  APA 326 - Ona ara l’Olorun wa

APA 326

 1. Ona ara l’Olorun wa,

 Ngba sise Re l’aiye;

 A nri ‘pase Re l’or’ okun,

 O ngun igbi l’esin.


2. Ona Re enikan ko mo,

 Awamaridi ni;

 O pa ise ijinle mo,

 O sin se bi Oba.


3. Ma beru mo, enyin mimo,

 Orun t’o su be ni,

 O kun fun anu: y’o rojo

 Ibukun s’ori nyin.


4. Mase da Oluwa l’ejo,

 Sugbon gbeke re le;

 ‘Gbati o ro pe o binu,

 Inu Re dun si o.


5. Ise Re fere ye wa na,

 Y’ o ma han siwaju;

 Bi o tile koro l’ oni,

 O mbo wa dun l’ola.


6. Afoju ni alaigbagbo

 Ko mo ‘se Olorun;

 Olorun ni Olutumo,

 Y’o m’ona Re ye ni. Amin.Yoruba Hymn  APA 326 - Ona ara l’Olorun wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 326- Ona ara l’Olorun wa  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post