Yoruba Hymn APA 332 - Olugbala mi, ife Re

Yoruba Hymn APA 332 - Olugbala mi, ife Re

Yoruba Hymn  APA 332 - Olugbala mi, ife Re

APA 332

 1. Olugbala mi, ife Re

 Ha tobi be si mi?

 Wo, mo f’ ife mi, okan mi,

 At’ aiya mi fun O.


2. Mo fe O nitori ’toye,

 Ti mo ri ninu Re;

 Mo fe O nitori iya,

 T’ o f’ ara da fun mi.


3. Bi Iwo ti je Olorun,

 T’ a f’ ogo de l’ ade;

 Iwo ko ko awo enia,

 T’ o kun fun iyonu.


4. ’Wo je k’ a bi O l’ enia,

 Sugbon ’Wo ko l’ ese;

 K’ awa le ri b’ Iwo ti ri,

 K’ a le se b’ O ti se.


5. K’ a dabi Re ninu ife,

 L’ ewa iwa mimo;

 B’ a ti nwoju Re, k’ a ma lo,

 L’ at’ ogo de ogo. Amin.



Yoruba Hymn  APA 332 - Olugbala mi, ife Re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 332-  Olugbala mi, ife Re   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post