Yoruba Hymn APA 333 - Ife orun, alailegbe

Yoruba Hymn APA 333 - Ife orun, alailegbe

Yoruba Hymn  APA 333 - Ife orun, alailegbe

APA 333

 1. Ife orun, alailegbe,

 Ayo orun, sokale:

 Fi okan wa se ’bugbe Re;

 Se asetan anu Re;

 Jesu, iwo ni alanu,

 Iwo l’ onibu ife;

 Fi igbala Re be wa wo,

 M’ okan eru wa duro.


2. Wa, Olodumare, gba wa,

 Fun wa l’ ore-ofe Re;

 Lojiji ni k’ o pada wa,

 Ma si fi wa sile mo:

 Iwo l’ a o ma yin titi,

 Bi nwon tin se ni orun;

 Iyin wa ki yio l’ opin,

 A o sogo n’nu ’fe Re.


3. Sasepe awa eda Re,

 Je ka wa lailabawon;

 K’ a ri titobi ’gbala Re,

 Li aritan ninu Re.

 Mu wa l’ at’ogo de ogo

 Titi de ibugbe wa:

 Titi awa o fi wole,

 N’ iyanu ife, iyin. Amin.Yoruba Hymn  APA 333 - Ife orun, alailegbe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 333 - Ife orun, alailegbe   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post