Yoruba Hymn APA 338 - Okan mi, Oluwa ni

Yoruba Hymn APA 338 - Okan mi, Oluwa ni

 Yoruba Hymn  APA 338 - Okan mi, Oluwa ni

APA 338

1. Okan mi, Oluwa ni,

 Jesu re ni, gboro Re;

 Jesu nso, O mba o so,

 Pe, elese, ’wo fe Mi?


2. ’Gbat’ a de o, Mo da o,

 O gb’ ogbe, Mo wo o san;

 ’Gb’ o sako, Mo mu o bo;

 Mo s’ okun re d’ imole.


3. Kike iya ha le mo

 Si omo re ti o bi?

 Lotito o le gbagbe,

 Sugbon Em’ o ranti


4. Ife t’Emi ki ye lai,

 O ga rekoja orun;

 O si jin ju okun lo,

 Ife alailegbe ni.


5. ’Wo fere r’ ogo Mi na,

 ’Gb’ ise ore-ofe tan;

 ’Wo o ba Mi gunwa po;

 Wi, elese, ’wo fe Mi?


6. Olori aroye mi

 Ni pe ife mi tutu;

 Sugbon mo fe O Jesu,

 A! mba le fe O ju yi! Amin. Yoruba Hymn  APA 338 - Okan mi, Oluwa ni

This is Yoruba Anglican hymns, APA 338-  Okan mi, Oluwa ni   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post