Yoruba Hymn APA 340 - Jesu Oluwa, Oba mi

Yoruba Hymn APA 340 - Jesu Oluwa, Oba mi

 Yoruba Hymn  APA 340 - Jesu Oluwa, Oba mi

APA 340

1. Jesu Oluwa, Oba mi,

 Gbohun mi nigbati mo npe,

 Gbohun mi lati ’bugbe Re,

 Rojo ore-ofe sile;

 Oluwa mi, mo feran Re,

 Je ki nle ma feran Re si.


2. Jesu, mo ti jafara ju,

 Ngo se le fe O b’o ti ye?

 Em’ o se le gb’ ogo Re ga,

 Ati ewa oruko Re.

 Oluwa mi. &c.


3. Jesu, kil’ o ri ninu mi,

 Ti ’fe na fi po to bayi?

 Ore Re si mi tip o to!

 O ta gbogbo ero mi yo!

 Oluwa mi, &c.


4. Jesu, ’Wo o je, orin mi,

 Tire l’ aiya at’ okan mi:

 Tire ni gbogbo ini mi,

 Olugbala, ’Wo ni temi:

 Oluwa mi, mo feran Re,

 Je ki nle ma feran Re si. Amin.



Yoruba Hymn  APA 340 - Jesu Oluwa, Oba mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 340-  Jesu Oluwa, Oba mi . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post