Yoruba Hymn APA 356 - Jesu npe wa, losan, lorun

Yoruba Hymn APA 356 - Jesu npe wa, losan, lorun

Yoruba Hymn  APA 356 - Jesu npe wa, losan, lorun

APA 356

 1. Jesu npe wa, losan, lorun,

 Larin irumi aiye;

 Lojojumo l’ a ngbohun Re

 Wipe, “Kristian, tele Mi.”


2. Awon Apostili ‘gbani,

 Ni odo Galili ni:

 Nwon ko ile, ona, sile,

 Gbogbo nwon si nto lehin.


3. Jesu npe wa, kuro ninu

 Ohun aiye asan yi;

 Larin afe aiye, O nwi

 Pe, “Kristian e feran Mi.”


4. Larin ayo at’ ekun wa,

 Larin lala on’ rorun;

 Tantan l’ o npe l’ ohun rara

 Pe, “Kristiani e feran Mi.”


5. Olugbala nip’ anu Re,

 Je ki a gbo ipe Re;

 F’ eti ‘gboran fun gbogbo wa,

 K’ a fe O ju aiye lo. Amin.Yoruba Hymn  APA 356 - Jesu npe wa, losan, lorun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 356- Jesu npe wa, losan, lorun  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post