Yoruba Hymn APA 357 - Kristian, ma ti ’wa ’simi

Yoruba Hymn APA 357 - Kristian, ma ti ’wa ’simi

Yoruba Hymn  APA 357 - Kristian, ma ti ’wa ’simi

APA 357

 1. Kristian, ma ti ’wa ’simi,

 Gbo b’ Angeli re ti nwi;

 Ni arin ota l’ o wa;

 Ma sora.


2. Ogun orun-apadi,

 T’ a ko ri, nko ’ra won jo;

 Nwon nso ijafara re;

 Ma sora.


3. Wo hamora-orun re,

 Wo losan ati loru;

 Esu ba, o ndode re;

 Ma sora.


4. Awon t’ o segun saju,

 Nwon nwo wa b’ awa ti nja;

 Nwon nfi ohun kan wipe,

 Ma sora.


5. Gbo b’ Oluwa re ti wi,

 Eniti iwo feran;

 F’ oro Re si okan re;

 Ma sora.


6. Ma sora bi enipe,

 Nibe ni ’segun re wa;

 Gbadura fun ’ranlowo;

 Ma sora. Amin.Yoruba Hymn  APA 357 - Kristian, ma ti ’wa ’simi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 357-Kristian, ma ti ’wa ’simi  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post