Yoruba Hymn APA 359 - Ma toju mi Jehofah nla

Yoruba Hymn APA 359 - Ma toju mi Jehofah nla

Yoruba Hymn  APA 359 - Ma toju mi Jehofah nla

APA 359

 1. Ma toju mi Jehofah nla,

 Ero l’aiye osi yi;

 Emi ko n’ okun, iwo ni,

 F’ ow’ agbara di mi mu:

 Onje orun, Onje orun,

 Ma bo mi titi lailai.


2. Silekun isun ogo ni,

 Orison imarale;

 Je ki imole Re orun

 Se amona mi jale:

 Olugbala, Olugbala,

 S’ agbara at’ asa mi.


3. ‘Gba mo ba te eba Jordan,

 F’ okan eru mi bale:

 Iwo t’ o ti segun iku,

 Mu mi gunle Kenaan ja:

 Orin iyin, Orin iyin

 L’ emi o fun O titi. Amin.Yoruba Hymn  APA 359 - Ma toju mi Jehofah nla

This is Yoruba Anglican hymns, APA 359- Ma toju mi Jehofah nla. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post