Yoruba Hymn APA 367 - E ma te siwaju, Kristian ologun

Yoruba Hymn APA 367 - E ma te siwaju, Kristian ologun

Yoruba Hymn  APA 367 - E ma te siwaju, Kristian ologun

APA 367

 1. E ma te siwaju, Kristian ologun,

 Ma tejumo Jesu t’o mbe niwaju;

 Kristi Oluwa wa ni Balogun wa,

 Wo! asia Re wa niwaju ogun,

 E ma te siwaju, Kristian ologun,

 Sa tejumo Jesu t’o mbe niwaju.


2. Ni oruko Jesu, ogun Esu sa,

 Nje Kristian ologun, ma nso si ’segun;

 Orun apadi mi ni hiho iyin.

 Ara, gbohun nyin ga, gb’ orin nyin soke

 E ma te siwaju, &c.


3. Bi egbe ogun nla, n’ Ijo Olorun,

 Ara, a nrin l’ona t’awon mimo rin;

 A ko yaw a n’ipa, egbe kan ni wa,

 Okan n’ireti, l’eko, okan n’ife.

 E ma te siwaju, &c.

 

4. Ite at’ ijoba, wonyi le parun,

 Sugbon Ijo Jesu y’o wa titi lai;

 Orun apadi ko le bor’ Ijo yi,

 A n’ileri Kristi, eyi ko le ye.

 E ma te siwaju, &c.


5. E ma ba ni kalo, enyin enia,

 D’ohun nyin po mo wa, l’orin isegun;

 Ogo, iyin, ola, fun Kristi Oba,

 Eyi ni y’o ma je orin wa titi.

 E ma te siwaju Kristian ologun,

 Sa tejumo Jesu t’o mbe niwaju. Amin.



Yoruba Hymn  APA 367 - E ma te siwaju, Kristian ologun

This is Yoruba Anglican hymns, APA 367- E ma te siwaju, Kristian ologun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post