Yoruba Hymn APA 368 - Amona okan at’ Oga

Yoruba Hymn APA 368 - Amona okan at’ Oga

Yoruba Hymn  APA 368 - Amona okan at’ Oga

APA 368

 1. Amona okan at’ Oga

 Awon ero l’ona orun,

 Jo ba wa gbe, ani awa

 T’a gbekele Iwo nikan;

 Iwo nikan l’a f’okan so,

 B’a ti nrin l’ona aiye yi.


2. Alejo at’ ero l’a je,

 A mo p’aiye ki se ’le wa:

 Wawa l’a nrin ’le osi yi,

 L’aisimi l’a nwa oju Re;

 A nyara s’ ilu wa orun,

 Ile wa titilai l’oke.


3. Iwo ti o rue se wa,

 T’ o si fi gbogbo re ji wa;

 Nipa Re l’a nlo si Sion,

 T’a nduna ile wa orun;

 Afin Oba wa ologo,

 O nsunmo wa, b’a ti nkorin.


4. Nipa imisi ife Re,

 A mu ona ajo wa pon;

 S’ idapo Ijo-akobi,

 A nrin lo si oke orun,

 T’awa t’ayo ni ori wa:

 Lati pade Balogun wa. Amin.
Yoruba Hymn  APA 368 - Amona okan at’ Oga

This is Yoruba Anglican hymns, APA 368- Amona okan at’ Oga  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post